Frequently Asked Questions Yoruba

FAQ is available in English, Yoruba, Egun, Ibo and Hausa. Click the laguage button to select your choice.


 • KÃ NI Ã NÌ PÃ NÃ LAGOS HOMS?

  +

  Lagos HOMS jéÌ£ ètò ìyáwó tí a fi nÌ kóÌ£ ilé t’ara eÌ£ni, ó sì jéÌ£ ìlànà oÌ£lóÌ£gboÌ£oÌ£gba tí àwoÌ£n olùgbé ÌpínleÌ£ Èkó lè fi jànfàní níní ilé ti ara woÌ£n.  Lagos HOMS yóò pèsè ìlànà èÌ£yáwó tí kò ni ni lara tí ó sì roÌ£rùn láti san ní ÌpínlèÌ£ Èko.

  ÌjoÌ£ba ÌpínlèÌ£ Èkó yóò:

  • Pèsè ibùgbé onírúurú èÌ£yà àti ìwòÌ£n tó dára tí owó rèÌ£ kò ni ni lára láti san, sí káàkiri ÌpínlèÌ£ Èko.
  • Pèsè ànfàní ètò èÌ£yáwó fikóÌ£lé fún àwoÌ£n olùgbé ÌpínlèÌ£ Èkó tí woÌ£n kò ní ilè síbi Kankan téÌ£lèÌ£ ní ÌpínlèÌ£ Èko.

  ÈrònÌgbà ètò yìí dálé mímú kí òÌ£pòÌ£ olùgbé ÌpínlèÌ£ Èkó ní ilé t’ara woÌ£n láìpéÌ£ oÌ£jóÌ£, tí eÌ£nikéÌ£ni kò fí nií rá ilé lóÌ£poÌ£w, èyí tó lè sàkóbà èrònÌgbà ÌjoÌ£ba pé kí òÌ£pòÌ£ ilé wà nílèÌ£ lóÌ£wóÌ£ tí kò ga ni lára.

 • ÃϿWOÌ£N WO NÃϿ ÃϿ NÌϿ PÃϿ NÃϿ ONÃϿBÃϿÃϿRÃϿ ÃϿKÃϿÌ£KÃϿÌ£?

  +

  Tí ìkóÌ£lé bá parí (keÌ£séÌ£ járí), ìgbìmòÌ£ Elétò ÈÌ£yáwó ÌkóÌ£lé ÌpínlèÌ£ Èkó yóò téÌ£wóÌ£gba àwoÌ£n ìlé náà, ìgbìmòÌ£ yìí ní yóò siséÌ£ àkóso ètò ìlèÌ£ pínpín.

  ÌgbìmòÌ£ Elétò ÈÌ£yáwó ÌkóÌ£lé yóò sì pe àwoÌ£n tó féÌ£ gba ilè sí íbí ètò ìyíkoto tí yóò maà wáyé lóòrèkóòrè béÌ£èÌ£ ni Ilé-IséÌ£ Olókòòwò Ìkólé ÌpínlèÌ£ Èkó (LBIC) yíó darí èÌ£yáwò tí àwoÌ£n tó bá yege yóò gbà fi ra ilèÌ£.  EÌ£ teÌ£ òÌ£gangan KÍ LÓ YEÌ£ KÍ N MÓÌ£? ní gbangba ayélujára (www.lagoshoms.gov.ng) tí eÌ£ bá tún féÌ£ gbóÌ£ èÌ£kúnréÌ£réÌ£ àlàye lórí ètò ìyáwó ìkóÌ£lé yìí.

 • BÃ WO NI ÃTÃ YÃÃ YÃÃ FI SÌ£EÃSÌ£E?

  +

  Tí ìkóÌ£lé bá parí (keÌ£séÌ£ járí), ìgbìmòÌ£ Elétò ÈÌ£yáwó ÌkóÌ£lé ÌpínlèÌ£ Èkó yóò téÌ£wóÌ£gba àwoÌ£n ìlé náà, ìgbìmòÌ£ yìí ní yóò siséÌ£ àkóso ètò ìlèÌ£ pínpín.

  ÌgbìmòÌ£ Elétò ÈÌ£yáwó ÌkóÌ£lé yóò sì pe àwoÌ£n tó féÌ£ gba ilè sí íbí ètò ìyíkoto tí yóò maà wáyé lóòrèkóòrè béÌ£èÌ£ ni Ilé-IséÌ£ Olókòòwò Ìkólé ÌpínlèÌ£ Èkó (LBIC) yíó darí èÌ£yáwò tí àwoÌ£n tó bá yege yóò gbà fi ra ilèÌ£.  EÌ£ teÌ£ òÌ£gangan KÍ LÓ YEÌ£ KÍ N MÓÌ£? ní gbangba ayélujára (www.lagoshoms.gov.ng) tí eÌ£ bá tún féÌ£ gbóÌ£ èÌ£kúnréÌ£réÌ£ àlàye lórí ètò ìyáwó ìkóÌ£lé yìí.

 • TA NI Ã LÃ RA ILÃÌ£?

  +

  Olùgbé ÌpínlèÌ£ Èkó tí oÌ£jóÌ£ orí rèÌ£ ti lé ní oÌ£dún mókànlélógún tí ó sì kógo ìlànà ìdánÌgájíá já lè lóÌ£wóÌ£ sí ètò yìí.

 • MO SÌ£ÃÌ£SÌ£ÃÌ£ TI ÃLà OÌ£BA Dà LÃÌ£YÃN OÌ£DÃN MÃTA, Ṣà MO LÃÌ£TÃÌ£ÃÌ£ LÃTI Rà NÃNà ÃWOÌ£N ILà NÃÃ?

  +

  EÌ£níkeÌ£ní tó bá yege ìlànà ìlóÌ£wóÌ£sí lè kòÌ£wé bèèrè.  SÌ£ùgbóÌ£n o, àkópà gboÌ£dòÌ£ jéÌ£ eÌ£ni tó nÌ gbé ÌpínlèÌ£ Èkó tí ó sì nÌ san owó orí rèÌ£ déédé.  ÈÌ£rí pé ó ti san owó orí f’ódidi oÌ£dún márùn-ún gboÌ£dòÌ£ wà (kí ó tóó kòÌ£wé bèèrè ilé).

 • Sà ÃWOÌ£N AKÃÌ£KÃÌ£ÃÌ£ NÃà LÃÌ£TẠ̃à ?

  +

  Òfin tó de ètò yìí ní pé eÌ£ni tí ó féÌ£ ra ilé gbóÌ£dòÌ£ kéÌ£se ìlànà ìlóÌ£wóÌ£sí já.  O gbọ̣́dòÌ£ pèsè èÌ£rí owó orí tó ti san f’ódidi oÌ£dún márùn-ùn àti èÌ£rí owó osÌ£ù tí yóò fi hàn pé ó lè máa san owó padà lósÌ£oosÌ£ù.  Tí àwoÌ£n akéÌ£kòÌ£óÌ£ bá wà nínú ìsòÌ£rí yìí, wóÌ£n lè kópa.

 • Ṣà ÃÌ£RÃÌ£ ILà RÃRà YÃà LÃÌ£WÃÌ£ OÌ£J&AT

  +

  EÌ£ni tó bá ti tó eÌ£ni oÌ£dún móÌ£kànlélógún lè lóÌ£wóÌ£ sí ètò yìí.  A ó f’òté lé iye tí oÌ£jóÌ£ orí gboÌ£dòÌ£ jé.  Ìkópa nínú ètò yìí dálé bí akópa sÌ£e ní agbaja àtí máa sanwò lósÌ£oosù sí.

 • Ṣà MO Là Wà EÌ£NÃKAN KÃNâRA?

  +

  Ó seése.  SÌ£ùgbóÌ£n èÌ£yin méjèèjì gboÌ£dòÌ£ tèÌ£wòÌ£n.  ÀjùmòÌ£ní ni ìwé àsÌ£eÌ£ ilé yóò jé tí eÌ£ bà yege.

 • IBO NI MO TÃ LÃ GBÃÌ£ ÃÌ£KÃNRÃÌ£RÃÌ£ ÃLÃYÃ NÃPA ÃWO&

  +

  EÌ£ loÌ£ sí gbàgede àyélujára wa http://www.lagoshoms.gov.ng/homes tí eÌ£ bá féÌ£ moÌ£ bí fíféÌ£ irúfé ilé àti agbègbè tí ilé wà.

 • MO NÃFÃÌ£ÃÌ£ Sà LAGOS HOMS ÃLÃNà WO Là RÃÌ£ MÃÌ£ OÌ£N?

  +

  JòÌ£wóÌ£ loÌ£ sí èÌ£roÌ£ ayélujára 5 easy steps tí o bá féÌ£ gba èÌ£kúnréÌ£réÌ£ àlàyé lórí àwoÌ£n ìgbésèÌ£ márùnún tí yóò soÌ£ éÌ£ di onílé.

 • ÃLà Nà OWà ÃSÌ£ÃTÃ? Ṣà MO Là GBA OWà MI PADà Tà MI à Bà YEGE

  +

  EÌ£gbèÌ£rún méÌ£wàá náírà péré ni.  Owó tí o ti san nígbà tí o feÌ£eÌ£ dá fóÌ£òÌ£mù padà kò sÌ£eé gbà padà.

 • Ṣà OHUN KAN Wà Tà MO GBÃÌ£DÃÌ£ FI KÃN FÃÌ£ÃÌ£Mà NÃGB&

  +

  ÀwoÌ£n àkoÌ£sílèÌ£ tí o gbóÌ£dòÌ£ fi kún fóÌ£òÌ£mù wà nínú fóÌ£òÌ£mù ó sì tún wà ní ayélujára wa.  JòÌ£wóÌ£ teÌ£ checklist of documents to submit with your Application.  (ÀwoÌ£n àkoÌ£sílèÌ£ tí o gbóÌ£dòÌ£ fi kún fóÌ£òÌ£mù ìlóÌ£wóÌ£sí reÌ£)

 • LÃÌ£YÃN ÃYÃKOTO, KÃ LÃ TÃN KÃN?

  +

  Tí o bá ti yege, ÀjoÌ£ LBIC á bèÌ£rèÌ£ isÌ£éÌ£ lórí ètò èÌ£yáwó reÌ£.  ÀjoÌ£ yìí á koÌ£ léÌ£tà sí eÌ£ pé kí o wá ra ilé.  Tí o bá ti gba léÌ£taeÌ£ ìpè, ó kù sí eÌ£ lóÌ£wóÌ£ pé kí o soÌ£ pé o gba láti ra ilé, kí ò wáá tèÌ£lé ìlànà tí àjoÌ£ LBIC là sílèÌ£, pàápàá jùloÌ£ fífaramóÌ£ sísan ìkó oÌ£gbòÌ£n nínú ìdá ọ̣góÌ£rùn-ún owo ilé ní àkóÌ£kóÌ£ tí àjoÌ£ náà là sílèÌ£.  LéÌ£yìn èyí, wà á toÌ£wóÌ£ boÌ£ ìwé ÌtalèÌ£ àti Ìwé Àdéùn ÈÌ£yáwó.  Nígbà náà ní kóÌ£kóÌ£róÌ£ ilé á di tì eÌ£.

 • TÃ MI Ã BÃ JEÌ£ NÃBI ÃYÃKOTO NÌ KÃÌ£?

  +

  O lè tún kòÌ£wé bèèrè ní àìmoye ìgbà bí o bá sÌ£e féÌ£, sÌ£ùgbóÌ£n, o níláti san owó ìsÌ£ètò fóÌ£òÌ£mù nígbàkúùgbà tí o bá kòÌ£wé bèèrè.

  SÌ£ùgbóÌ£n, tí kò bá ju osÌ£ù méÌ£ta loÌ£ léÌ£yìn tí o kùnà tí o tún fí kèÌ£wé bèèrè fóÌ£òÌ£mù mìíràn, tí àkoÌ£sílèÌ£ reÌ£ kò sì yí padà, a yòÌ£nda re léÌ£nu títoÌ£wóÌ£ boÌ£ fóÌ£òÌ£mù mìíràn.  Ohun tí o kù fún e ni pé kí o sÌ£ètò ìbúra pé o ti ní fóÌ£òÌ£mù nílèÌ£ téÌ£lèÌ£.

 • BÃWO NI MO SÌ£E FÃÌ£ MÃÌ£ PÃ MO YEGE ÃTÃ ÃÌ£YÃWÃ ÃFIKÃ&IGRAV

  +

  Kò le rárá.  JòÌ£wóÌ£ teÌ£ “Resources Tab” ní ojú èÌ£roÌ£ ayélujára LagosHOMS.  IbèÌ£ ni wàá ti moÌ£ ohun tí ó yeÌ£ kí o sÌ£e.  O sì tún lè lo èÌ£roÌ£ àkàyé Mortgage calculator tí wàá fi moÌ£ iye tí ó yeÌ£ kí o máa san lósÌ£oosù.

 • ÃLÃ NI ÃLÃ ORÃ ÃTÃ ÃÌ£YÃWÃ LAGOS HOMS?

  +

  Iye èlé kò dúró sí ojú kan.  TeÌ£ òÌ£gangan ibí kì o lè mo iye èlé tó wà lóde báyìí.

 • OÌ£DÃN MÃLÃÃ NI N ÃÃ FI SAN OWÃ TÃ MO YÃ?

  +

  OÌ£dún méÌ£wàá ni.

 • BÃWO NÃ MO SÌ£E LÃ MOÌ£ IYE TÃ N ÃÃ SAN PADÃ?

  +

  Tí o bá fèÌ£ moÌ£ àpapòÌ£ iye tí wàá san padà jòÌ£wóÌ£ teÌ£ mortgage calculator.  Ànfàni wà láti moÌ£ gbogbo ìgbésèÌ£ tó jeÌ£ móÌ£ ètò yìí àti bí ètò èÌ£yáwó reÌ£ yóò sÌ£e di àmúsÌ£e.  Wà á moÌ£ iye tí èÌ£dáwó reÌ£ olósÌ£oosù kà nínú èlé tí o ní láti san àti iye tí o kù nílèÌ£ láti fi san ojú owó tí o yá.

 • ÃLÃ NÃ ÃPÃN TÃ MO GBÃÌ£DÃÌ£ DÃ?

  +

  EÌ£ni tó bá yege ètò ìyíkoto yóò kóÌ£kóÌ£ san owo àsansílèÌ£ tì ìkó rèÌ£ jéÌ£ oÌ£gbòÌ£n nínú ìdá oÌ£góÌ£rùn-ún, iye owo ilé.  Eyí ni a pè ní Ìpín ÈÌ£dáwó

 • ÃWOÌ£N OWÃ WO LÃ TÃN KÃ NÃ SÃSAN TÃ MO BÃ GBA OWÃ NYA ÃFIRALÃ?

  +

  Owó tí a fi nÌ sÌ£e àsepé ètò ilé rírà nìkan náà ni ti owó ìfòntèÌ£lù àti ìforúkoÌ£sílèÌ£ wà nínú reÌ£.  SÌ£ùgbóÌ£n ní gbàrà tí o bá téÌ£wóÌ£ gba ilé re, o ní láti san owó ìní tàbí ilé gbígbé bí owó máàdámidófò lórí ilé, owo ìsÌ£àkóso àwoÌ£n ohun kòseémánìí owó ìlò ilèÌ£ àti àwoÌ£n àbùdá mìíràn.  Iye owó tí oò máa san wà lóÌ£wóÌ£ iye owo ilé re.

 • Ṣà DANDAN NI Pà Kà N SÌ£ÃTà ÃFOWÃPAMÃÌ£ LÃÌ£DÃÌ£ LBIC

  +

  BéÌ£èÌ£ ni.  O ní láti sÌ£íwèé ìfowòpamóÌ£ lóÌ£dòÌ£ LBIC nibí tí a óò máa san owó tí o nÌ dá padà lósÌ£oosù sí.  O gbóÌ£dòÌ£ máa dá owó sínú àpò ìfowópamóÌ£sì reÌ£ lósÌ£oosù.

 • Ṣà MO Là MÃA FI ÃWà SÃÌ£WÃDOWà Tà GBÃGBà Kà à TÃà Y&

  +

  Ó sÌ£eésÌ£e.  O lè san ìwe sòÌ£wédowó tí oÌ£jóÌ£ gbígba rèÌ£ sún síwájú èyí tí a óò máa fi san owo ilé rsÌ£ lósÌ£oosÌ£ù.

 • NJÃÌ£ Ã SÌ£EÃSÌ£E PÃ KÃ WÃÌ£N MÃA YOÌ£ OWÃ NYÃ ÃRAL&ATI

  +

  Kò sÌ£eésÌ£e rárá.  SÌ£ùgbóÌ£n o lè fún àwoÌ£n òÌ£gá ilé ìfowópamóÌ£ tí owó reÌ£ wà, ní bánkì mìíràn pé kí wóÌ£n máa yoÌ£ èÌ£dáwó olósÌ£oosÌ£ù reÌ£ sínú àkoÌ£sílèÌ£ ìfowópamóÌ£ reÌ£ tí o wà ní LBIC.

 • ÃÌ£Nà WO NI MO Là GBà Bà MÃà SE ÃYÃÌ£Wà IYE OWÃǸYà Tà Kà FÃN MI LÃTI SAN?

  +

  NípasèÌ£ kíkàn sí òÌ£gá tó wà nídìí ètò bíbá àwoÌ£n oníbàárà sÌ£epòÌ£ ní LBIC.

 • Ṣà MO Là SAN JU ÃKà OÌ£GBÃÌ£N NÃNà ÃDà OÌ£GÃÌ£RÃN-ÃN LOÌ£ Tà MO Bà LÃKUN RÃÌ£?

  +

  Rárá o.  Kò gboÌ£dòÌ£ ju ìkó oÌ£gbòÌ£n nínú ìdá oÌ£góÌ£rún-ún loÌ£, béÌ£èÌ£ ni iye tí o gbóÌ£dòÌ£ máà san lósÌ£oosÌ£ùu kò gboÌ£dòÌ£ ju ìkó oÌ£gbòÌ£n nínú ìdá oÌ£góÌ£rùn-ún owó osÌ£ù reÌ£ loÌ£.

 • Kà Là TÃN RÃÌ£ MÃÌ£ ÃSÌ£ÃTà ÃKOÌ£SÃLÃÌ£ OW&ATIL

  +

  Tí o bá ti yege ètò ìyíkoto, a óò taari ìwé reÌ£ sí òÌ£dòÌ£ àjoÌ£ LBIC níbi tí woÌ£n yóò bèÌ£rèÌ£ isÌ£éÌ£ lórí rèÌ£.  TeÌ£ èÌ£roÌ£ ayélujára sí processing of your mortgage kì o lè moÌ£ ìgbésèÌ£ sÌ£ìseÌ£-n-teÌ£lé tó nÌ wáyé lórí ìsètò owóǹyá ìralèÌ£ reÌ£.

 • ÃGBÃ WO NI ÃTÃ ÃKOÌ£SÃLÃÌ£ NÃÃ MÃA KÃÌ£SEÌ£ JÃR&ATIL

  +

  Ó wà lóÌ£wóÌ£ ìgbà tí o bá parí gbogbo ìlànà tí àjoÌ£ LBIC là sílèÌ£, sùgbóÌ£n kò gboÌ£dòÌ£ gbà ju oÌ£gbòÌ£n oÌ£jóÌ£ loÌ£.

 • SÃ O SÌ£EÃSÌ£E PÃ KÃ N MÃA SÌ£E ÃYÃÌ£WÃ ÃPELE ÃTÃ ÃK

  +

  BéÌ£èÌ£ ni, ó sÌ£eésÌ£e tí o bá teÌ£ Track my Application ní èÌ£roÌ£ ayélújara.

 • Ṣà MO Là SAN OWÃǸYà MI TÃN Kà OÌ£DÃN MÃÌ£WÃà TÃÃ

  +

  Rárá o, oÌ£dún méÌ£wàá ni eÌ£ni tó yáwó fi ra ilé lábéÌ£ ètò Lagos HOMS gbóÌ£dòÌ£ fi san owo rèÌ£, ó kéré tán.

 • Sà MO Là FI KÃN IYE Tà Mà NÌ SAN LÃSÌ£OOSÌ£Ã?

  +

  BéÌ£èÌ£ ni, ó sÌ£eésÌ£e, tí sÌ£ísÌ£e àfikùn owóndá olósÌ£oosÌ£ù kò bá níí dín oÌ£dún meÌ£wàá kù.

 • Tà MO Bà KÃNà LÃTI SAN OWÃǸYà OṢà KAN TÃBà Tà OWà Tà Mà NÌ Dà PADà Bà PÃÌ£ Kà à TÃà Dà ÃÌ£DÃÌ£ ÃJOÌ£ LBIC NÌKÃ?

  +

  Tí o bá kùnà léÌ£èÌ£meta léraléra, a lè ti ilé reÌ£ pa.  PípéÌ£ láti san owó olósÌ£oosÌ£ù lè sÌ£okùnfà pé kí o san ogún ìkó nínú ìdá oÌ£góÌ£rùn-ún owo olósÌ£oosÌ£ù lé, o dára kí o tètè loÌ£ seóÌ£dòÌ£ àjoÌ£ LBIC ní kété tí o bá ní ìsÌ£òrò sísan owó padà.

 • KÃ NI Ã NÌ PÃ NÃ TITLE DOCUMENT (ÃWE ÃKOÌ£SÃLÃÌ£ ÃSOÌ£-OHUN-DI TâEÃ

  +

  Ìwé yìí jéÌ£ ìwé àdéùn ìyóÌ£nda ilé fún ni f’ódidi oÌ£dún móÌ£kàndínlóÌ£góÌ£rùn-ún dín oÌ£jóÌ£ kan tí ÌjoÌ£ba ÌpínlèÌ£ Èkó sètò.

  A ó sÌ£ètò ìwé yìì fún eÌ£ pé kí ó foÌ£wóÌ£ síi ní kété tí o bá ti kéÌ£seÌ£ ètò èÌ£yáwó já, sÌ£ùgbóÌ£n lòÌ£dóÌ£ àjoÌ£ LBIC ni yóò wà títí tí wàá fi san owo ilé tán, tí o sì parí sísan owóǹyá ìralèÌ£.

 • Ṣà ÃTà YÃà TÃN LÃÌ£WÃÌ£ MÃDÃÃMIDÃFO NÃNÃ?

  +

  BéÌ£èÌ£ ni o.  Ó di dandan pé kí o sÌ£ètò mádàámidófò lórí ilé, kí o lè rí ohun gbójúlé lásìkò ìsÌ£èÌ£lèÌ£ ewu iná àti àwoÌ£n àjálù mìíràn.  Ara ìlànà tí àjoÌ£ LBIC là sílèÌ£ ni èyí í sÌ£e.  IrúféÌ£ ètò mádàámidófò mìíràn tó tún wà sÌ£ùgbóÌ£n tí kò poÌ£n dandan ni Mortgage Protection Insurance.  SÌ£ùgbóÌ£n ó dára pé kí o sÌ£ètò yìí nítorí pé ó nÌ dáàbòbò ni lásìkò ìsÌ£èÌ£léÌ£ ikú tàbí nì àkókò ìjànbá ara agbénisÌ£ánlèÌ£ doÌ£jóÌ£ ikú.

 • Ṣà MO Là FI ILà Tà MO Rà RÃÌ£NTÃ?

  +

  Rárá.  “Gba ilé, gbé’nú ilé reÌ£” (ONÍLÉ NÍ NÌ GBÉE) ní ètò yìí ní póÌ£nbélé.  ÌyeÌ£n ni pé dandan ni, o gbóÌ£dòÌ£ gbé inú ilé tí o rà.  Kò sÌ£eésÌ£e pé kí o ra ilé kí o fi réÌ£ntì.  ÀyèÌ£wò yóò máa wáyé lóòrèkóòrè láti ní ìdánilójú pé onílé ló nÌ gbé inú ilé reÌ£.

 • TÃ N Ã BÃ Ã TÃ Ã SAN OWÃNYÃ MI TÃN, TÃ MO SÃ FÃÌ£ TA ILÃ NÃÃ, K&ATI

  +

  Pé o féÌ£ ta ilé reÌ£ láì jéÌ£, pé o tí sánwo tán kò sÌ£eésÌ£e torí pé bí ìgbà tí o fèÌ£ gba owó eÌ£tóÌ£ èÌ£yáwó reÌ£ padà ló jéÌ£, àjọ̣ LBIC nìkan ló sì lè dáwólé ìgbésèÌ£ yìí.  Tí o kò bá féÌ£ sÌ£e móÌ£, kàn sí ÌgbìmòÌ£ Elétò ÌsÌ£àkóso Owónyá ÌralèÌ£ (ÌkóÌ£lé) LMB.

 • Ṣà MO NÃLà AGBEÌ£JÃÌ£RÃ?

  +

  BéÌ£èÌ£ ni.  A gbà é nímòÌ£ràn pé kí o gba ìmòÌ£ràn lóÌ£dòÌ£ agbeÌ£jóÌ£rò, kí ó le tóÌ£ eÌ£ sóÌ£nà lórí àkoÌ£síléÌ£ òfin.

 • TANI YÃÃ MÃA MÃJÃTÃ ILÃ MI TÃ MO BÃ TI RÃ Ã TÃN?

  +

  ÀwoÌ£n ilé isÌ£éÌ£ elétò olùsÌ£àmójútó ohun kòsÌ£eémánìí wà, tí ÌgbìmóÌ£ LMB yàn.  OjúsÌ£e àwoÌ£n ilé isÌ£éÌ£ náà dálé sÌ£ísÌ£e àkóso àti àmójútó ìta ilé, ìpèsè ohun ìsÌ£àkóso ní àgbègbè kan pàtó.  ÀwoÌ£n onílé ni yóò máa san owo isÌ£éÌ£ fún àwoÌ£n Alákòóso ohun kòsÌ£eémánìí (ohun isÌ£éÌ£ kòsÌ£eémánìí).  SÌ£ùgbóÌ£n onílé ni yóò máa sÌ£e isÌ£éÌ£ àtúnsÌ£e inú ilé reÌ£.

 • ABÃNIWÃLÃ NI MÃ, MO SÃ FÃÌ£ RA ILÃ LÃÌ£PÃÌ£ FÃN ÃWOÌ£N ONÃBÃÃRÃ MI, KÃ NI MO LÃ SÌ£E?

  +

  NíwòÌ£n ìgbà tó jéÌ£ pé tí àwoÌ£n tí yóò máa gbé inú ilé tí wóÌ£n rà ni ètò yìí dálé, a gbà éÌ£ nímòÌ£ràn pé kí o soÌ£ fún àwoÌ£n oníbàárà reÌ£ pé kí wóÌ£n kòÌ£wé bèèrè irúféÌ£ ile tí wóÌ£n féÌ£ ní tààràtà.

***APPLICANTS ARE STRONGLY ADVISED TO SEEK THE ADVICE OF A LAWYER TO ASSIST THEM THROUGH THE MORTGAGE APPLICATION PROCESS


Back to TopBack to Top